Información
Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o. Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o. Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun. Òrìsà jè ...
mostra más
Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o. Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o.
Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun. Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun.
mostra menos
Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun. Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun.
Cantos a Odu
Cantos a Odu
7 FEB. 2020 · Ofun Meji Olowo, Ofun Meji Olowo, Ofun Meji Olowo,
Mo be yin, ki e fun mi l owo ati ohun rere gbogbo.
Eyin li e nfun Alara lowo ki e fun emi, naa l owo ati ohun rere gbogbo.
Eyin li e nfun Ajero l owo, ki e fun emi naa l owo ati ohun rere gbogbo.
Eyin le e nfun Orangun Ile - Ila l'owo, ki e masai fun emi naa l'owo ati ohun rere gbogbo ati be ebee titi lo. Ofun Meji Olowo. Ase.
7 FEB. 2020 · Ose Meji, Ose Meji, Ose Meji,
Mo be yin, ki e fun mi ni agbara,
Ki nsegun awon ota mi loni ati ni gbogbo ojo aye mi, kiemaa bami fi ise se gbogbo awon eniti nwa
Ifarapa ati beebee fun mi.
Ki e jeki ngbo ki nto ki npa awu sehin. Ose Meji. Ase.
7 FEB. 2020 · Otura Meji, Otura Meji, Otura Meji,
Mo be yin, ki e bami tu imo o s o, ki e ba mi tumo Aje,
Ki e bami tumo awon amonis eni, imo awon afaimoniseni ati imo awon asenibanidaro, ti nro ibi si mi ka. Otura Meji. Ase.
7 FEB. 2020 · Ko de si omo láte. Omo wun mi ju ileke.
Ko de si omo láte. Omo wun mi ju ileke.
7 FEB. 2020 · Oturupon Meji, Oturupon Meji, Oturupon Meji,
Mo be yin, ki e jeki Iyawo mi r 'omo gbe pon,
Ki o r'omo gbe s ire, ki e jeki oruko mi han si rere, ki ipa mi laye ma parun.
Omi kiiba 'le kiomani 'pa, ki'mi ni'pa re laye ati beebee.
Oturupon Meji. Ase.
7 FEB. 2020 · Okò mi sí, okò mì gbò.
Okò mi sì, okò mì gbò.
Èbúté ire l oko mi lo.
Èbúté ire l oko mi lo.
7 FEB. 2020 · Osa Meji, Osa Meji, Osa Meji,
Mo be yin, ki e jeki ndi arisa-ina, akotagiri ejo fun awon ota,
Kieso mi di pupo gun rere, ki'mi r'owo san owo ori, kimi r'owo san awin Orun mi ati beebee.
Osa Meji. Ase.
7 FEB. 2020 · Ogunda Meji, Ogunda Meji, Ogunda Meji,
Mo be yin, kiedai ni'de Arun Ilu ejo, egbese ati beebee, ki e d a'ri ire owo,
Ise oro omo ola emigigun, aralile ati beebee s odo mi,
Ki e da mi ni abiyamo tiyoo bimo rere ti won, yoo gb'ehin s i - sinu aye ati beebee.
Ogunda Meji. Ase.
7 FEB. 2020 · Awún de wa. Awún dèrò.
Orí ire l'awun nwe.
Odán nbi, Odán nre.
Odán ti esele ibùdó o.
Odán ti esele ibùdó o.
7 FEB. 2020 · Sàkòtó mo léwà. Awo ire dun bo níf è. Sàkòtó mo léwà. Awo ire dun bo níf è.
Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o. Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o. Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun. Òrìsà jè ...
mostra más
Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o. Ayé Sèrén ti dun, o dun ju oyin l o.
Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun. Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun.
mostra menos
Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun. Òrìsà jè ayé mi o dun, Aláyun gbáláyun.
Información
Autor | Carlos Flores Guillén |
Organización | Carlos Flores Guillén |
Categorías | Educación |
Página web | - |
- |
Copyright 2024 - Spreaker Inc. an iHeartMedia Company